الفيل

تفسير سورة الفيل

الترجمة اليورباوية

Yorùbá

الترجمة اليورباوية

ترجمة معاني القرآن الكريم للغة اليوربا ترجمها الشيخ أبو رحيمة ميكائيل أيكوييني عام الطبعة 1432هـ .

﴿بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَٰنِ الرَّحِيمِ أَلَمْ تَرَ كَيْفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصْحَابِ الْفِيلِ﴾

Ṣé o ò rí bí Olúwa rẹ ti ṣe ọ̀rọ̀ ìjọ elérin ni?

﴿أَلَمْ يَجْعَلْ كَيْدَهُمْ فِي تَضْلِيلٍ﴾

Ṣé kò sọ ète wọn di òfo bí?

﴿وَأَرْسَلَ عَلَيْهِمْ طَيْرًا أَبَابِيلَ﴾

Ó sì rán àwọn ẹyẹ níkọ̀níkọ̀ sí wọn.

﴿تَرْمِيهِمْ بِحِجَارَةٍ مِنْ سِجِّيلٍ﴾

Wọ́n ń jù wọ́n ní òkúta amọ̀ (t’ó ti gbaná sára).

﴿فَجَعَلَهُمْ كَعَصْفٍ مَأْكُولٍ﴾

Ó sì sọ wọ́n di bíi èrúnrún koríko àjẹkù gbígbẹ.

الترجمات والتفاسير لهذه السورة: