الإسلام والديمقراطية

Esin Islam ati Oro nipa Eto Oselu Tiwa- ntiwa (Demokiresi)


محاضرة بلغة اليوربا، فيها بيان الحكم الشرعي في مشاركة المسلم في الانتخابات، وحكم تشكيل الأحزاب السياسية والمشاركة فيها.
1- Eleyi ni oro nipa ohun ti o je ojuse Musulumi nibi ibo didi ati idajo Islam lori kikopa ninu idibo.<br /> 2- Itesiwaju nipa ohun ti Islam so lori eto oselu tiwa- ntiwa (Demokiresi), olubanisoro menu ba idajo esin lori dida egbe oselu sile ati kikopa ninu re, o si tun so nipa ojuse eniti o ba fe gbegba fun ipo oselu.